Jẹ́nẹ́sísì 31:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní àsìkò tí àwọn ẹran ń gùn, mo la àlá mo sì ri pé àwọn òbúkọ tí wọ́n ń gun àwọn ẹran jẹ́ oní-tótòtó, onílà àti alámì.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:9-19