Jẹ́nẹ́sísì 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Olúwa Ọlọ́run ké pe ọkùnrin náà pé, “Níbo ni ìwọ wà?”

Jẹ́nẹ́sísì 3

Jẹ́nẹ́sísì 3:7-15