Jẹ́nẹ́sísì 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti Ísáákì di arúgbó, ojú rẹ̀ sì ti di bàìbàì tóbẹ́ẹ̀ tí kò le ríran. Ó pe Ísọ̀ àkọ́bí rẹ̀, ó sì wí fún un pé, “Ọmọ mi”,Ísọ̀ sì dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Jẹ́nẹ́sísì 27

Jẹ́nẹ́sísì 27:1-9