Jẹ́nẹ́sísì 25:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jákọ́bù fún Ísọ̀ ní oúnjẹ àti ọbẹ̀. Ó jẹ ẹ́, ó sì jáde lọ.Báyìí ni Ísọ̀ ṣe aláìka ogún ìbí rẹ̀ sí.

Jẹ́nẹ́sísì 25

Jẹ́nẹ́sísì 25:29-34