Jẹ́nẹ́sísì 24:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ó bá sì wí fún mi pé, “Mu ún, èmi yóò sì tún pọn omi fún àwọn ràkunmí rẹ pẹ̀lú,” Jẹ́ kí ẹni náà jẹ́ ẹni tí Olúwa yàn fún ọmọ Ábúráhámù, olúwa mi.’

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:41-47