Jẹ́nẹ́sísì 24:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun náà dáhùn pé, “Mu, olúwa mi,” ó sì yára sọ ìkòkò omi náà ka ọwọ́ rẹ̀, ó sì fún-un mu.

Jẹ́nẹ́sísì 24

Jẹ́nẹ́sísì 24:12-23