Jẹ́nẹ́sísì 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

jáde lọ láti bá Bérà ọba Ṣódómù, Bírísà ọba Gòmórà, Ṣínábù ọba Ádímà, Ṣémébérì ọba Ṣébóímù àti ọba Bélà (èyí-ni nì Ṣóárì) jagun.

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:1-7