Jẹ́nẹ́sísì 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ìjòyè Fáráò sì rí i, wọ́n ròyìn rẹ̀ níwájú u Fáráò, Wọ́n sì mú un lọ sí ààfin,

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:13-20