Jẹ́nẹ́sísì 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, sọ pé, arábìnrin mi ni ìwọ, wọn yóò sì ṣe mí dáradára, a ó sì dá ẹ̀mí mi sí nítorí tìrẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:12-20