Jẹ́nẹ́sísì 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wà láàyè fún ọdún mẹ́talénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ébérì, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:12-24