Jẹ́nẹ́sísì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kúsì sì bí Nímúrọ́dù, èyí tí ó di alágbára àti jagunjagun ní ayé.

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:1-17