Jẹ́nẹ́sísì 10:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èyí ni ìran àwọn ọmọ Nóà: Ṣémù, Ámù àti Jáfétì, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi.

2. Àwọn ọmọ Jáfétì ni:Gómérì, Mágógì, Mádáì, Jáfánì, Túbálì, Méṣékì àti Tírásì.

3. Àwọn ọmọ Gómérì ni:Áṣíkénásì, Rífátì àti Tógárímà.

Jẹ́nẹ́sísì 10