Jẹ́nẹ́sísì 1:30-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Àti fún àwọn ẹranko inú igbó àti ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ohun afàyàfà: gbogbo ohun tó ní èémí ìyè nínú ni mo fi ewéko fún bí oúnjẹ.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

31. Ọlọ́run sì rí àwọn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àsálẹ́ àti òwúrọ̀, ó jẹ́ ọjọ́ kẹfà.

Jẹ́nẹ́sísì 1