Jákọ́bù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ gbàgbọ́ pé Ọlọ́run kan ní ó ń bẹ; ó dára! Àwọn ẹ̀mí èṣù pẹ̀lú gbàgbọ́ bẹ́ẹ̀, wọ́n sì wá rìrì.

Jákọ́bù 2

Jákọ́bù 2:12-24