Ísíkẹ́lì 48:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ilẹ̀ tí ẹ̀yin o fi ìbò pín ní ogún fún àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì, wọ̀nyí sì ni ìpín wọn,” ní Olúwa Ọlọ́run wí.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:24-35