Ísíkẹ́lì 48:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn òsìsẹ́ láti ìlú ńlá náà, tí ó ń dáko níbẹ̀ yóò wá láti gbogbo àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.

Ísíkẹ́lì 48

Ísíkẹ́lì 48:12-29