Ísíkẹ́lì 47:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó bi mí léèrè, pé: “Ọmọ ènìyàn, ǹjẹ́ o rí èyí?”Lẹ́yìn náà ó mú mi padà sí etí odò.

Ísíkẹ́lì 47

Ísíkẹ́lì 47:1-12