Ísíkẹ́lì 47:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí yìí ní ohun tí Olúwa Ọba wí: “Ìwọ̀nyí ni àwọn ààlà tí ìwọ yóò fi pín ilẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí ogún ìní ní àárin àwọn ẹ̀yà méjìlá Ísírẹ́lì, pẹ̀lú ìpín méjì fún Jóṣéfù.

Ísíkẹ́lì 47

Ísíkẹ́lì 47:10-18