Ísíkẹ́lì 47:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn apẹja yóò dúró ní etí bèbè odò; láti Éńgédì títí dé Énégíláémù àyè yóò wa láti tẹ́ àwọ̀n wọn sílẹ̀. Orísìírísìí ẹja ni yóò wà gẹ́gẹ́ bí ẹja omi òkun ńlá.

Ísíkẹ́lì 47

Ísíkẹ́lì 47:9-13