Ísíkẹ́lì 45:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní agbègbè ibi mímọ́, wọn ya ibi kan sọ́tọ̀ kí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n ìgbọ̀nwọ́ gígùn àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ní fífẹ̀. Ní inú rẹ ni ilẹ̀ ti a yà sọ́tọ̀ fún Olúwa yóò wà, ìyẹn ibi mímọ́ jùlọ.

Ísíkẹ́lì 45

Ísíkẹ́lì 45:1-4