Ísíkẹ́lì 45:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éfà àti batì gbọdọ̀ jẹ́ bákan náà, kí bátì tí ó gba ìdàmẹ́wàá hómérì, àti ẹfa ìdámẹ́wàá hómérì: Hómérì ni kí ó jẹ́ òṣùnwọ̀n tí wọn yóò lò fún méjèèjì.

Ísíkẹ́lì 45

Ísíkẹ́lì 45:8-12