Ísíkẹ́lì 44:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí tí ó dára jùlọ nínú gbogbo àkọ́so èso àti ti ẹ̀bùn pàtàkì yóò jẹ́ ti àwọn àlùfáà. Ẹ ní láti fún wọn ní ìpín àkọ́kọ́ nínú èso ilẹ̀ yìí kí ìbùkún lè wà lórí gbogbo ilé yìí.

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:22-31