Ísíkẹ́lì 44:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èmi ni kì ó jẹ́ ogún tí àwọn Àlùfáà yóò ní. Ẹ kò gbọdọ̀ fún wọn ni ìpín kankan ní Ísírẹ́lì; Èmi ni yóò jẹ́ ìpín wọn.

Ísíkẹ́lì 44

Ísíkẹ́lì 44:21-31