Ísíkẹ́lì 41:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹpẹ ìrúbọ kan tí a fi igi ṣe wà, gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, àwọn igun rẹ̀, ìsàlẹ̀ rẹ̀ àti ògiri rẹ́ jẹ́ igi. Ọkùnrin náà sọ fún mi pé, “Èyí yìí ní tẹ́ḿpìlì tí ó wà ní iwájú Olúwa.”

Ísíkẹ́lì 41

Ísíkẹ́lì 41:12-26