Ísíkẹ́lì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dojú kọ ibùdó ogun Jérúsálẹ́mù, na ọwọ́ rẹ sí i, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìlú náà.

Ísíkẹ́lì 4

Ísíkẹ́lì 4:3-17