Ísíkẹ́lì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsìnyìí, Ìwọ ọmọ ènìyàn, mú amọ̀ ṣíṣù kan, gbé e sí iwájú rẹ, kí o sì ya àwòrán Jérúsálẹ́mù sí orí rẹ̀.

Ísíkẹ́lì 4

Ísíkẹ́lì 4:1-10