Ísíkẹ́lì 31:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlá ńlá ní ẹwà rẹ̀ jẹ́,pẹ̀lú títẹ́ rẹrẹ ẹ̀ka rẹ̀,nítorí gbòǹgbò rẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀sí ibi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi wà.

Ísíkẹ́lì 31

Ísíkẹ́lì 31:6-15