Ísíkẹ́lì 31:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní, oṣù kẹ́ta ọdún kọkànlá, ọrọ Olúwa tọ̀ mí wá:

2. “Ọmọ ènìyàn, sọ fún Fáráò Ọba Éjíbítì àti sí ìjọ rẹ̀:“ ‘Ta ní a le fi wé ọ ní ọlá ńlá?

Ísíkẹ́lì 31