Ísíkẹ́lì 26:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà, báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Kíyèsí i, èmí dojú kọ ọ́ ìwọ Tírè, Èmi yóò sì jẹ́ kí orílẹ̀ èdè púpọ̀ dide sí ọ, gẹ́gẹ́ bí òkun tíi ru sókè.

Ísíkẹ́lì 26

Ísíkẹ́lì 26:1-7