Ísíkẹ́lì 23:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oun náà ní ìfẹ́kúùfẹ́ sí ará Ásíríà àwọn gómìnà àti àwọn balógun, jagunjagun nínú aṣọ ogun, àwọn tí ń gun ẹṣin, gbogbo àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin arẹwà.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:7-18