Ísíkẹ́lì 21:31-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Níbẹ̀ ni èmi yóò ti ṣe ìdájọ́ yín,èmi yóò sì fi èémí ìbínú gbígbónámi bá yín jà.

32. Ẹ̀yin yóò jẹ́ èpò fún iná náà,a yóò ta ẹ̀jẹ̀ yin sórí ilẹ̀ yín,a ki yóò rántí yín mọ́;nitorí èmi Olúwa ní ó ti wí bẹ́ẹ̀.’ ”

Ísíkẹ́lì 21