Ísíkẹ́lì 20:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ fẹ́ dájọ́ wọn bí? Ìwọ fẹ dájọ́ wọn bí ọmọ ènìyàn? Nítorí náà fi gbogbo ìwà ìríra baba wọn kò wọ́n lójú,

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:1-9