Ísíkẹ́lì 20:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, mo mú wọn jáde ní ilẹ̀ Éjíbítì mo sì mú wọn wá sínú ihà.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:8-17