Ísíkẹ́lì 15:7-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Èmi yóò dojúkọ wọ́n. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn ti jáde kúrò nínú iná kan síbẹ̀ iná mìíràn yóò pàpà jó wọn. Nígbà tí mo bá sì dojúkọ wọ́n, ẹ ó sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

8. Èmi yóò sọ ilé náà di ahoro nítorí ìwà àìsòótọ́ wọn, ni Olúwa Ọlọ́run wí.”

Ísíkẹ́lì 15