Ísíkẹ́lì 14:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Díẹ̀ nínú àwọn alàgbà Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ mi, wọ́n sì jókòó níwájú mi,

2. Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:

Ísíkẹ́lì 14