Ísíkẹ́lì 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran àti àfọ̀ṣẹ wọn jẹ́ èké. Wọ́n wí pé, “Olúwa wí” nígbà tí Olúwa kò rán wọn, síbẹ̀ wọ́n fẹ́ kí Olúwa mú ọ̀rọ̀ wọn ṣẹ.

Ísíkẹ́lì 13

Ísíkẹ́lì 13:1-16