Ísíkẹ́lì 13:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsin yìí, ọmọ ènìyàn, dojú kọ àwọn ọmọbìnrin ènìyàn rẹ tí wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ láti inú èrò ọkàn wọn, sọtẹ́lẹ̀ sí wọn

Ísíkẹ́lì 13

Ísíkẹ́lì 13:12-20