Ísíkẹ́lì 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kérúbù sì gbé ìyẹ́ wọn sókè pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì sì wà lókè orí wọn.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:20-25