Ísíkẹ́lì 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn yóò padà síbẹ̀, wọn ó sì mú gbogbo àwòrán ìríra rẹ̀ àti ìbọ̀rìṣà kúrò.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:16-22