Ìfihàn 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì kẹ́ta sì fún ìpè tirẹ̀, ìràwọ̀ ńlá kan tí ń jó bí fìtílà sì bọ́ láti ọ̀run wá, ó sì bọ́ sórí ìdámẹ̀ta àwọn odò ṣíṣàn, àti sórí àwọn orísun omi;

Ìfihàn 8

Ìfihàn 8:9-13