Ìfihàn 6:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi sì rí i nígbà tí Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà sí ọkàn nínú èdìdì wọ̀nyí, mo sì gbọ́ ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà ń wí bí sísán àrá pé, “Wá, wò ó!”

2. Mo sì wò ó, kíyèsí i, Ẹṣin funfun kan: ẹni tí ó sì jókòó lórí i rẹ̀ ní ọrùn kan; a sì fi adé kan fún un: ó sì jáde lọ láti ìṣẹ́gun dé ìsẹ́gun.

Ìfihàn 6