Ìfihàn 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti sí áńgẹ́lì ìjọ ní Láódékíá kọ̀wé:Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni ẹni tí ń jẹ́ Àmín wí, ẹlẹ́rìí olódodo àti olóòótọ́, olórí ìṣẹ̀dá Ọlọ́run:

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:11-17