Ìfihàn 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn kan sì ti ibi ìtẹ́ náà jáde wá, wí pé:“Ẹ máa yin Ọlọ́run wa,ẹ̀yin ìránṣẹ́ rẹ̀ gbogbo,ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù rẹ̀,àti èwe àti àgbà!”

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:1-12