Ìfihàn 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti àwọn ọba ayé, tí ó ti ń bá a ṣe àgbérè, ti wọn sì ń hùwà wọ̀bìà, yóò sì pohùnréré ẹkún lé e lórí, nígbà tí wọn bá wo èéfín ìjóná rẹ̀.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:1-17