Ìfihàn 16:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yìnyín ńlá, tí ọkọkan rẹ̀ tó talẹ́ntì ní ìwọ̀n, sì bọ́ lù àwọn ènìyàn láti ọ̀run wà: Àwọn ènìyàn sì sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run nítorí ìyọnu yìnyín náà; nítorí tí ìyọnu rẹ̀ náà pọ̀ gidigidi.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:18-21