Ìfihàn 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi fún un, láti fi ẹ̀mí fún àwòrán ẹranko náà kí ó máa sọ̀rọ̀ kí ó sì mu kí a pa gbogbo àwọn tí kò foríbalẹ̀ fún àwòrán ẹranko náà.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:10-18