Ìfihàn 11:18-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Inú bí àwọn orílẹ̀-èdè, bẹ́ẹ̀ni ìbínú rẹ̀ ti dé,àti àkókò láti dá àwọn òkú lẹ́jọ́,àti láti fi èrè fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wòlíì,àti àwọn ènìyàn mímọ́, àti àwọn tí o bẹ̀rù orúkọ rẹ̀,àti ẹni kékeré àti ẹni ńlá;àti láti run àwọn tí ń pa ayé run.”

19. A sì ṣí tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run sílẹ̀ ní ọ̀run, a sì ri àpótí májẹ̀mu nínú tẹ́ḿpìlì rẹ̀. Mọ̀nàmọ́ná sì kọ, a sì gbọ́ ohùn, àrá sì sán, ilẹ́ sì mi, yìnyín ńlá sì bọ́.

Ìfihàn 11