Ìfihàn 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì tọ ańgẹ́lì náà lọ, mo sì wí fún pé, “Fún mi ní ìwé kékeré náà.? Ó sì wí fún mi pé, ‘Gbà kí o sì jẹ ẹ́ tan: yóò dàbí oyin.’ ”

Ìfihàn 10

Ìfihàn 10:1-11