Hósíà 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alágbèrè ni gbogbo wọnwọ́n gbóná bí ààrò àkàràtí o dáwọ́ kíkọná dúró, lẹ́yìnìgbà tí o ti pò iyẹ̀fun tán, títí ìgbà tí yóò wú.

Hósíà 7

Hósíà 7:1-11