Hósíà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ Éfúráímù; Kín ló tún kù tí mo ní ṣe pẹ̀lú ère òrìṣà?Èmi ó daba! lóhùn, èmi o sì ṣe ìtọ́jú rẹ.Mo dàbí igi tó ń fi gbogbo ìgbà tutù,èso tí ìwọ ń so si ń wá láti ọ̀dọ̀ mi.”

Hósíà 14

Hósíà 14:3-9